Ìwé Ìròhìn
fún Àmúgbòòrò, Ìlọsíwájú àti Ìdàgbàsókè
Yorùbá
Ẹ káábọ̀, ẹ̀yin
alárá wa. Ẹ̀yà
Yorùbá wà káàkiri gbogbo àgbáyé. Wọ́n pọ̀, wọ́n
gbọ́n, wọ́n ní òye, àsà, ọ̀làjú, ètò bí
a se ń se Ìlú àti àkóso. Bẹ́ẹ̀ni wọ́n sì jáfáfá.
A kò se iyèméjì pé bí ẹ̀yà Yorùbá bá rí ọwọ́
mú lágbàńlá-ayé, Aláwọ̀dúdú rí ọwọ́
mú nìyan. Ìdà kejì ọ̀rọ̀ yìi rí bẹ́ẹ̀,
àmọ́ a ò gbàdúrà rẹ̀.
Àdúrà nìkan kò tó sá. A gbọdọ̀
sisé tọ̀ ọ́ ni. Èyí ló gbún wa ní kẹ́sẹ́ láti
dá Ìwé Ìròhìn Afọnrere YORÙBÁ ỳií sílẹ̀.
Èdè Yorùbá ni a ó maa fi kọ ọ́. A ó ma tu díẹ̀ nínù
Ìròhìn wa sí èdè Gẹ̀ẹ́sì, èdè Faransé àti
Śpáníisì ní Ìdákọ̀ọ̀kan.
Kí ẹ máa bá wa kálọ.
Ẹ fi Ìwé yín sọwọ́ sí wa ní afonrereyoruba@yahoo.com
Ire o.
JÀRE ÀJÀYÍ
Olùdásílẹ̀ tí í tún
se Olóòtú Àgbà
Ọ̀pọ̀
nǹkan ni ẹ ó ma rí kà nínú Ìwé Ìròhìn yí lóòrèkóòrè.
Afọnrere ẁa fún gbogbo m̀ut́uḿuẁa.
Ẹ wo ̀Ìtọ́ka tó wà lókè láti fi ka ọ̀kan-ò-jọ̀kan
ohun ti a tẹ̀ sínú AfọnrereYorùbá. Àkà gbádùn ni.
Ẹ o rí Ìròhìn káàkiri àgbáyé tó jẹ mọ́
Yorùbá nínú rẹ̀. Ìròhìn láti Nàijíríà,
Àmẹ́ríkà, ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́ẹ́sì, Ìbáábá
(the Diaspora),Ìwọ̀ Afrika, Ùrúgúayè, Brasiili, Kuba (Cuba) àti ibi gbogbo
ní àgbáyé tí Yorùbá ti ń se bẹbẹ.
Ẹ máa kàá, kí ẹ sì máa kọ̀we
yiń sí wa,
Ire o.
Olóòtú.
Fún ̀ipolongo, ̀Ì̀ḿugb̀òor̀o ̀ati ̀ilọs̀iẃaj́u
Yor̀ub́a.
̀Ifara-ẹni ĺeti: A woye pe Apẹ-̀it̀ẹẃe
(Keyboard) ti a l̀o ́n gb́e ǹnkan ̀aj̀eji j́ade ĺoŕI Kọmṕut̀a
̀awọn kan. Ńitori ̀eyi ni a se ̀Akọwọĺe yii ni ̀ẹ̀ẹmeji
- ̀ọkan pẹlu Ape-itẹwe Ḱọnyin, ̀ekeji pẹĺu Apẹ-itẹwe (ati
f́ọǹnti) miran
Oĺòot́u.
E kaabo,
eyin alara wa. Eya Yoruba wa kaakiri gbogbo agbaye. Won po, won gbon, won ni oye, asa, olaju, eto bi a se n se ilu ati
akoso. Beeni won si jafafa. A ko se iyemeji pe bi eya Yoruba ba ri owo mu lagbanla-aye, Alawodudu ri owo mu niyan. Ida keji
oro yii ri bee, amo a o gbadura re.
Adura nikan
ko to sa. A gbodo sise to o ni. Eyi lo gbun wa ni kese lati da iwe irohin Afonrere YORUBA yii sile. Ede Yoruba ni a o maa
fi ko o. A o ma tu die ninu irohin wa se ede Geesi, ede Faranse ati Spaniisi ni idakookan.
Ki e maa
ba wa kalo.
E fi iwe
yin sowo siwa ni afonrereyoruba@yahoo.com
Ire o.
JARE AJAYI
Oludasile
ti i tun se Olootu Agba.