Afonrere YORUBA Gbode

Abawole Home Bonvenido Bonvenu | Igbelaruge Yoruba | Irohin Lakotun | oloyenewsgbode.tripod.com | Konyin, opon-itewe titun wo'ja agbaye | Irohin | Irohin | Iforowero Interview Page | Ikede | Photo Album Page | Leta Mailbag | E kowe si wa lori ero okan yin tabi nipa Yoruba: afonrereyoruba@yahoo.com E seun | Archives | New Page Title

E kaabo si Afonrere YORUBA
Afonrere
Iwe Irohin fun imugbooro, ilosiwaju ati idagbasoke Yoruba

Ìwé  Ìròhìn fún Àmúgbòòrò, Ìlọsíwájú àti Ìdàgbàsókè Yorùbá

Ẹ káábọ̀, ẹ̀yin alárá wa. Ẹ̀yà Yorùbá wà káàkiri gbogbo àgbáyé. Wọ́n pọ̀, wọ́n gbọ́n, wọ́n ní òye, àsà, ọ̀làjú, ètò bí a se ń se Ìlú àti àkóso. Bẹ́ẹ̀ni wọ́n sì jáfáfá. A kò se iyèméjì pé bí ẹ̀yà Yorùbá bá rí ọwọ́ mú lágbàńlá-ayé, Aláwọ̀dúdú rí ọwọ́ mú nìyan. Ìdà kejì ọ̀rọ̀ yìi rí bẹ́ẹ̀, àmọ́ a ò gbàdúrà rẹ̀.

Àdúrà nìkan kò tó sá. A gbọdọ̀ sisé tọ̀ ọ́ ni. Èyí ló gbún wa ní kẹ́sẹ́ láti dá Ìwé Ìròhìn Afọnrere YORÙBÁ ỳií sílẹ̀. Èdè Yorùbá ni a ó maa fi kọ ọ́. A ó ma tu díẹ̀ nínù Ìròhìn wa sí èdè Gẹ̀ẹ́sì, èdè Faransé àti Śpáníisì ní Ìdákọ̀ọ̀kan.

Kí ẹ máa bá wa kálọ.

 

Ẹ fi Ìwé yín sọwọ́ sí wa ní afonrereyoruba@yahoo.com

Ire o.

JÀRE ÀJÀYÍ

Olùdásílẹ̀ tí í tún se Olóòtú Àgbà

 

Ọ̀pọ̀ nǹkan ni ẹ ó ma rí kà nínú Ìwé Ìròhìn yí lóòrèkóòrè.

Afọnrere ẁa fún gbogbo m̀ut́uḿuẁa.

Ẹ wo ̀Ìtọ́ka tó wà lókè láti fi ka ọ̀kan-ò-jọ̀kan ohun ti a tẹ̀ sínú AfọnrereYorùbá. Àkà gbádùn ni.

 

Ẹ o rí Ìròhìn káàkiri àgbáyé tó jẹ mọ́ Yorùbá nínú rẹ̀. Ìròhìn láti Nàijíríà, Àmẹ́ríkà, ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́ẹ́sì, Ìbáábá (the Diaspora),Ìwọ̀ Afrika, Ùrúgúayè, Brasiili, Kuba (Cuba) àti ibi gbogbo ní àgbáyé tí Yorùbá ti ń se bẹbẹ.

Ẹ máa kàá, kí ẹ sì máa kọ̀we yiń sí wa,

Ire o.

Olóòtú.  

 Fún ̀ipolongo, ̀Ì̀ḿugb̀òor̀o ̀ati ̀ilọs̀iẃaj́u Yor̀ub́a.

̀Ifara-ẹni ĺeti:  A woye pe Apẹ-̀it̀ẹẃe (Keyboard) ti a l̀o ́n gb́e ǹnkan ̀aj̀eji j́ade ĺoŕI Kọmṕut̀a ̀awọn kan. Ńitori ̀eyi ni a se ̀Akọwọĺe yii ni ̀ẹ̀ẹmeji - ̀ọkan pẹlu Ape-itẹwe Ḱọnyin, ̀ekeji pẹĺu Apẹ-itẹwe (ati f́ọǹnti) miran

Oĺòot́u.

E kaabo, eyin alara wa. Eya  Yoruba wa kaakiri gbogbo agbaye. Won po, won gbon, won ni oye, asa, olaju, eto bi a se n se ilu ati akoso. Beeni won si jafafa. A ko se iyemeji pe bi eya Yoruba ba ri owo mu lagbanla-aye, Alawodudu ri owo mu niyan. Ida keji oro yii ri bee, amo a o gbadura re.

Adura nikan ko to sa. A gbodo sise to o ni. Eyi lo gbun wa ni kese lati da iwe irohin Afonrere YORUBA yii sile. Ede Yoruba ni a o maa fi ko o. A o ma tu die ninu irohin wa se ede Geesi, ede Faranse ati Spaniisi ni idakookan.

Ki e maa ba wa kalo.

E fi iwe yin sowo siwa ni afonrereyoruba@yahoo.com

Ire o.

JARE AJAYI

Oludasile ti i tun se Olootu Agba.

 

 

 

Opo nnkan ni e o ri ma ri ka ninu iwe irohin yi loorekoore.

Diamonds 2

Afonrere wa fun gbogo mutumuwa.

E wo Itoka to wa loke lati fi ka okan-o-jokan ohun ti a te sinu AfonrereYoruba. Akagabadun ni. E o ri irohin kaakiri agbaye to je mo Yoruba ninu re. Irohin lati Naijiria, Amerika, ile Geesi, Ibaaba (Diaspora), Uruguaye, ati bee bee lo.

E maa kaa ki e si maa kowe yin si wa,

Ire o.

Olootu.

AfonrereYORUBA: Fun ipolongo, imugbooro ati ilosiwaju Yoruba kaakiri agbanla-aye. E-mail: afonrereyoruba@yahoo.com