Make your own free website on Tripod.com

E fi iwe yin lori Yoruba sowo si wa fun agbeyewo ninu AfonrereYoruba.

Akagbadun ni iwe yii

Afonrere je ona lati ri pe awon omo Yoruba nile, loko, ati lehin odi jo n gbo ara won. O tun wa fun awon ti o wa ni ona jinjin, o fi kan awon to je pe irandiran won lo je Yoruba gege bi awon to wa ni Amerika ati ni Karibia.

Afonrere YORUBA Gbode

Ikede

Abawole Home Bonvenido Bonvenu | Igbelaruge Yoruba | Irohin Lakotun | oloyenewsgbode.tripod.com | Konyin, opon-itewe titun wo'ja agbaye | Irohin | Irohin | Iforowero Interview Page | Ikede | Photo Album Page | Leta Mailbag | E kowe si wa lori ero okan yin tabi nipa Yoruba: afonrereyoruba@yahoo.com E seun | Archives | New Page Title

Ibi yii ni e o ti maa ri okan-o-jokan oro ti awon onkawe wa n so. A n ri iwe gba ni orisirisi ede - paapaa julo ede Oyinbo ati ede Spaniisi. A o maa gbe awon iwe yii jade ni ede ti onkowe fi ko won pelu atipale soki ni ede Yoruba. E ma ba wa kalo. Ire o. Olootu - Jare Ajayi

 AWON OJO TI AWON ENIYAN WA N SE AJODUN ORISIRISI NI ILE KARIBIANI Itumo won ni Yoruba ti o fi de ori onka osu ni Yoruba n bo laipe.

Enrique Gonzalez ti orile-ede Uruguay lo fi sowo si wa. A dupe.

Eyi ni agekuru okan lara awon leta ti a ri gba laipe yii ni ede Spaniisi. A gbe die jade si laipe pelu itumo won si ede Yoruba. E o ri pe Afonrere ti n gberegejige, o ti gbarada- Yoruba, ede to yaayi to si lew jojo, ti di ohun ti araye n saaba (mmd). Sugbonm, ise si wa niwaju wa o. A gbodo mura. Oluwa a fun wa se, ase.

Estimado amigo Jare:

Gracias por su respuesta, y por traducir al Yoruba. Me agradaría mucho entender más ese hermoso idioma. Aunque aguardo sus comentarios sobre mi artículo, le respondo a sus preguntas.1. Uno: Queremos enseñar los hispanicos la lengua Yoruba. No sera dificil aprendrer.

Consigue aquí las mejores y mas recientes ofertas de trabajo en América Latina y USA:

 

A

B

C

1

Orisa

Candomblé

Batuque

2

Ossayin     Osanyin

12 de enero  Osu Kinni

25 de abril

3

Ode

20 de enero

21 de enero

4

Iemojá

2 de febrero

2 de febrero

5

Ogun

23 de abril

23 de abril

6

Exu

13 de junio

29 de junio

7

Naná

26 de julio

*

8

Obaluaiyé

16 de agosto

**

9

Omolú

17 de diciembre

**

10

Ibeije

27 de Setiembre

6 de enero

11

Xangô

30 de setiembre

30 de setiembre

12

Iansa (Iyámesan)

4 de diciembre

4 de diciembre

13

Oxum

8 de diciembre

8 de diciembre

14

Oxumaré

8 de diciembre

*

15

Osanlá (***)

25 de diciembre

25 de diciembre

16

Sonponnô

*

17 de Diciembre

17

* No cultuado

   

18

** En Batuque, Omolú y Obaluaiyé son considerados cualidades de Sonponnô (Xapaná)

   

19

*** El término Osanlá (Oxalá) nuclea a los Orisa "fun fun". Entre ellos Osanguiyán, Osalufâ, etc.

    

Books

Agbajo owo ni a fi n soya

Iwe Fun kika

Movies

E je ki a maa mo ero yin nipa ohun ti n lo ni ile Kaaro-oo-jire ati nipa awon omo Yoruba nibikibi kaakiri agbaye.

E fi iwe yin sowo si afonrereyoruba@yahoo.com

E seun.

Ajoni wa ni Afonrere. Bi e ba ri ona ti idagbasoke yoo fi de ba igbekale re, e jowo e je ki a mo. A dupe.

AfonrereYORUBA: Fun ipolongo, imugbooro ati ilosiwaju Yoruba kaakiri agbanla-aye. E-mail: afonrereyoruba@yahoo.com